Home iroyin Kò sí ìpínlẹ̀ tó ní iléesẹ́ tó Ogun – Amosu
iroyin - September 17, 2017

Kò sí ìpínlẹ̀ tó ní iléesẹ́ tó Ogun – Amosu

Gomina Ibikunle Amosu ti ipinle Ogun lo n salaye idi ti awon ko se fi owo yepere mu eto aabo. O ni “lati okeere ni oloju jinjin ti n mu ekun sun” ati wi pe “ maa fi oko mi da ona, ojo kan naa ni a n kọ̀ọ́” ni ko je ki awon gba awon omo ipanle laaye rara ni ipnle Ogun.

Amosu ni nnkan buruku ko gbodo sele si ipinle Ogun nitori pe, ipinle naa nikan ko lo maa fara gbaa, o maa kan gbogbo Naijiria nitori awon ileese orisiirisii to wa ni ipinle naa.

O ni eyi lo maa n je ki oun se ipade oloore-koore pelu awon alaabo ipinle naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…