Home iroyin Ìpínlẹ̀ Niger pàdánù ènìyàn àádọ́ta nínú ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú omi
iroyin - September 17, 2017

Ìpínlẹ̀ Niger pàdánù ènìyàn àádọ́ta nínú ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú omi

Abule kiri ni ipinle Benue lo padanu eniyan aadota ni oni pelu ojo arooroda kan to ro, to si se akoba gidi fun oko oju omi to n lo jeje re. Awon oku eniyan bii mejila ni won ko tii le so ibi ti won danu si bayii ninu ijamba oko oju omi naa.

Awon ajo to nimo nipa oju ojo ti wa se ikilo pe , ki o sora fun afojudi omi ni asiko yii nitori ojo odun yii to po maa je ki awon opo agbegbe maa si omi won sile ko to ba nnkan won je.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…