Home LÁGBO ÀRÍYÁ Emi ati omo mi: Timi Dakolo fi awon omo re yangan
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 13, 2017

Emi ati omo mi: Timi Dakolo fi awon omo re yangan

 

Akorin ti a mo si Timi Dakolo ti ke gbajare idunnu lori bi awon omo re se n dgab kiakia o, se ibi agba ba dagba de, omo a ba a nibe.

O se afihan awon omo re meteeta, ti awon naa si dara bii egbara.

O ni oun woye pe werewere ni won n dagba sii. Bi won ba fi bebi sere lonii, won a maa beere cartoon ori telifisan lola. O ni awon omo ti won n mu miliki lanaa ti wa di ei to n ba oun ja si eba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…