Home iroyin Kín ló dé? Coach Onigbinde fẹ́ kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ lárúgbó ara
iroyin - September 11, 2017

Kín ló dé? Coach Onigbinde fẹ́ kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ lárúgbó ara

Lokolaya gbodo maa gba adura nigba gbogbo, tori ko si igba ti darudapo ko le de laarin won.
Iru eyi lo n sele lowo ninu ile adari agbaboolu Super Eagles tele, iyen Coach Adegboyega Onigbinde.
Odun to n bo ni baba naa yoo pe ogorin odun (80 yeas) sugbon o ti gbe iyawo re, Iyaafin Abiona, lo si ile ejo ni Ibadan, pe ki adajo tu igbeyawo awon ka.
Onigbinde so nile ejo pe obinrin naa ni agidi, o si je onijagidijagan to le se ipalara fun eniyan.
Iyaafin Abiona ni ko ri bee, o ni oun ko fe kuro nile oko oun, to si je pe adajo ti sun ejo naa siwaju.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…