Home LÁGBO ÀRÍYÁ Nitori orin, Busola Oke fi oko re silu oyinbo
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 9, 2017

Nitori orin, Busola Oke fi oko re silu oyinbo

 

O ti to ojo meta akorin emi, Busola Oke, ti lo fara pamo si ilu oyinbo.

Eyi sele leyin igbeyawo, tori oke okun ni oko re n gbe.

Sugbon o ti pinnu lati pada si Naijiria bayii.  O fe pada si isi orin kiko. O ni oun ti salaye fun baale oun tori oun ko fe ki igbeyawo pa ebun orin ti oun ni patapata.

O si ti setan lati gbe awo orin meji jade.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…