Home iroyin Abúlé Ancha ní ìpínlẹ̀ Pleateau pàdánù èèyàn ogún
iroyin - September 9, 2017

Abúlé Ancha ní ìpínlẹ̀ Pleateau pàdánù èèyàn ogún

Ose to koja ni ede aiyede waye ni aarin Fulani daran-daran ati awon ara adugbo Ancha, ti o si mu emi Fulani kan lo. Ose yii ni o dabi igba ti awon Fulani naa wa gbesan pada, ti eniyan ogun si je Olorun nipe nigba ti opo eniyan fara pa yanna-yanna.

Aare Mohammadu  Buhari faju ro si isele naa, o ni ko ki n se nnkan to dara rara lati maa ja ija to le mu emi lo. Oga olopaa adugbo naa si fi da awon ara ilu loju pe awon ti fowo sinkun ofin mu eniyan marun-un, nigba ti awon si n fi da awon ara abule naa loju pe owo maa te awon to ku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…