Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mi ò lè tẹ̀ síwájú nínú orin kíkọ –Wizkid
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 6, 2017

Mi ò lè tẹ̀ síwájú nínú orin kíkọ –Wizkid

Gbajumọ olorin Ayọ Balogun ti gbogbo eeyan mọ si Wizkid lo ti jẹ ki awọn olulfẹ ẹ mọ pe oun o le tẹsiwaju ninu ere-orin eyi to n lọ lọwọ nitori ilera ara. O sọ eyi lori twitter ni ana to si n rawọ ẹbẹ si awọn ololufẹ ẹ. O rọ wọn ki wọn maa fi adura ran oun lọwọ ati pe oun fẹ fi akoko ailera ara yi faramọ awọn ọmọ titi ti ara fi maa le.

Ninu iroyin yi kan naa lo ti sọ pe ti oun ba ku nisinyi awọn eeyan ṣi maa sọrọ oun titi aye nitori iṣẹ ti oun ti ṣe silẹ ko le parun. O jẹ ko da awọn ololufẹ ẹ loju pe ọjọ kokandinlọgbọn osu yii ni oun ma tẹsiwaju ninu ere-orin naa ni ilu London ti awọn agbegbe to ku maa tẹlee leseese.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…