Home Orisirisi Ighalo kò tẹ̀ lófin FIFA ló múu gba káàdì
Orisirisi - September 4, 2017

Ighalo kò tẹ̀ lófin FIFA ló múu gba káàdì

Ojo jimo, ojo kinni, osu kesan-an yii ni iko agbaboolu orileede Naijiria fi iya ayo merin si odo je awon iko ti orileede Cameroon. Inu idije naa ni oludari boolu naa ti fun Odion Ighalo to je agbaboolu Naijiria ni kaadi ki o lo sora re.

Gbogbo awon eniyan lo wa n gbee poori enu pe olojoro ni Refiri naa, won ni ofin FIFA ni ki agbaboolu ma se yo ayo poro to ba gba boolu wole alatako re nipa bibo ewu sile. Igba ti o ya ni ajo FIFA wa salaye pe ajo awon ko gba ki eniyan polowo oja ti ko sanwo fun tabi ki o polongo esin tabi asa.

Ajo FIFA ni labe aso ti Ighalo si soke ni awon ti ri akole “I love Jesus” ni eyi to lodi sofin ajo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…