Home Orisirisi Ẹ má sọ Boko Haram D’Ọlọ́run – Lai Mohammed
Orisirisi - September 4, 2017

Ẹ má sọ Boko Haram D’Ọlọ́run – Lai Mohammed

Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii, Alhaji lai Mohammed ni o n ba awon oniroyin soro yii ni ilu Ikoyi, Eko ni ojo Sonde, ojo keta osu kesan-an yii.

O ni awon oniroyin wa lara awon to n je ki eegun won maa ran. O ni ko dara ki a maa royin awon eni ibi naa bi eni pe won n se araye loore gidi. Minisita ni gbogbo agbara ni ijoba to wa lode yii n sa lati segun awon eniyan buruku yii. O ni oun si ni igbagbo pe awon yoo segun won dandan laipe.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…