Home iroyin Èyí ni GSM nọ́ḿbà ọ̀gá ọlọ́pàá tuntun fún Ìpínlẹ̀ Èkó
iroyin - September 3, 2017

Èyí ni GSM nọ́ḿbà ọ̀gá ọlọ́pàá tuntun fún Ìpínlẹ̀ Èkó

Lati je ki ohun awon ara Oki maa tete de odo Oga Olopaa tuntun ni Ipinle Eko, Alagba Edgar Imohimi, o ti te  atejade  nomba foonu re.

Imohimi lo ropo Fatai Owoseni.

Ti  laasigbo  lab ba sele, ti  e so Dr fi to oga olopaa naa leti ni  warasasa, nomba ti e  o pe ni 08099990483.

Abenugan fun olu ileese olopaa ni  Eko, Ogbeni Olarinde Famous-Cole lo se atejade naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…