Home iroyin Dírẹ́bà sálọ lẹ́yìn tó pa ọlọ́kadà mẹ́ta
iroyin - September 2, 2017

Dírẹ́bà sálọ lẹ́yìn tó pa ọlọ́kadà mẹ́ta

 

Isele buruku kan ti se ni Okitipupa ni Ipinle Ondo, nigba ti direba (awako) moto Toyota Picnic kan pa olokada meta.

Bi isele naa se se tan ni okunrin naa na papa bora.

A gbo pe niwaju General Hospital to wa ni ilu naa ni isele yii gbe sele.

Won ni awon olokada meteeta wa lori okada kan, to si jo pe osibitu naa ni won n lo.

Isele naa fa ki awon egbe olokada ilu naa se iwode nla.

Alukoro awon olopaa ni Ipinle naa, Ogbeni Femi Joseph, ni otito ni isele naa se, to si je pea won ti n sise lori re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…