Home Orisirisi Ọdún Iléyá: MC Olúọmọ rọ̀jò àdúrà
Orisirisi - September 1, 2017

Ọdún Iléyá: MC Olúọmọ rọ̀jò àdúrà

 

 

Gbajugbaja oga onimoto, Alhaji Musiliu Akinsanya, ti a mo si MC Oluomo, dupe lowo Allah ni idaji oni, nigba to n kan si awon ololufe re ati Musulumi kaakiri agbaye lori alaja odun Ileya.

Ni pataki, MC Oluomo rojo adura le awon ololufe re ati gbogbo eniyan lori.

O gbadura fun ilosiwaju ati anikun owo, to si fi kun pe ipa ota ko ni ka eni kookan wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…