Home Orisirisi Allahu Akbar! Ọmọ Naijiria márùn-ún ti kú sí Mecca
Orisirisi - August 30, 2017

Allahu Akbar! Ọmọ Naijiria márùn-ún ti kú sí Mecca

Kadara lau!
Marun-un ninu awon omo Naijiria to wa ni Haaji ti odun yii ni won ti ku ni Mecca o.
Eyi sese di mimo lati owo Alaga Igbimo Haahi ni orile-ede yii, iyen National Hajj Commission, Alhaji Abdullahi Muhammed.
Sugbon ko tii so oruko awon ti oro kan.
O ni awon ko le tii se bee tori awon gbodo koko so oro isele naa fun awon molebi eni oro kan.
Ki Olorun fori jin awon ti olojo de ba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…