Home LÁGBO ÀRÍYÁ Iponju lo le mi kuro ni yunifasiti – Olamide
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 27, 2017

Iponju lo le mi kuro ni yunifasiti – Olamide

 

Gbajugbaja akorin hip-hop, Olamide, ti so pe iponu ni ko je ki oun pari eko oun ni Tai Solarin University of Education, Ijagun, ni Ijebu Ode.

O ni idile alaini ni oun ti wa tori awon obi oun ko lowo rara.

Lamide wa fi kun un pe sugbon nigba ti oun mu ebun ti Olorun fun oun lo, ti oun si sise karakara, oun wa di eni to goke agba, ti oun si rowo saye.

Akorin naa so oro yii lasiko to n ba awon omo ile iwe Ipinle Ogun soro, nibi eto olude kan ti ijoba Ibikunle Amosun se fun won ni Ewekoro.

O gba awon omo naa niyanju pe ki won foju si eko won; ki won ebun won lo; ki won si tepa mo’se daadaa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…