Home iroyin Orílèèdè yí ti ń súnmọ́ àkókò ìtúra rẹ̀ -Imaamu Ota.
iroyin - August 26, 2017

Orílèèdè yí ti ń súnmọ́ àkókò ìtúra rẹ̀ -Imaamu Ota.

Imaamu agba Mohammed Sadiku Buhari ti mosalasi nla ilu Ota nipinle Ogun ti fi gbogbo olugbe orileede yii lokan bale lose to koja nilu naa pe ojo itura ti setan lati ro sori ilu yii laifakoko sofo.Ninu oro re,imaamu agba keji l’Otta to si ti lo odun merinlelogun nipo naa kesi gbogbo musulumi ododo lati tunbo fi araa won han gege bi olujosin ododo ni gbogbo igba ninu iwa,oro ati isee won,Imaamu ro won lati se afihan ife si gbogbo eeyan lasiko odun Ileya to n kanlekun losu to n bo paapa julo awon elesin miran.Nipari,Imaamu agba lu gbogbo olugbe ilu abinibii re to je Awori ponbele ati elesin islam nilu Otta fun alaafia to n ti ara won joba nibe leyii to n fa ilosiwaju ba ilu naa ati ipinle Ogun lapapo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…