Home Orisirisi Oba mejillelogbon leekan soso: Awon omo Ibadan gbe ija lobaloba lo s’ori Facebook
Orisirisi - August 26, 2017

Oba mejillelogbon leekan soso: Awon omo Ibadan gbe ija lobaloba lo s’ori Facebook

Gomina Ipinle Oyo, Aenito Abiola Ajimobi, dan mewaa wo ni Ibadan lojo Jimoo, nigba to gbe oba mejilelogbon miiran dide ni Ibadan ati agbegbe re.

Ere ni opo eniyan koko pe e nigba ti Ajimobi ni ohun ti ijoba fe se niyen, eyi ti Olobadan ati opo eniyan miiran ko fara mo.

Bi ijoba Ajimobi se n fun awon oba tuntun naa ni iwe ase ni awuyewuye n lo kaakiri.

IROYIN OWURO woye pe lori ero alatagba naa, oro naa n ja ranin-rain.

Lori Facebook lojo Jimoo si owuro oni, opo eniyan lo se atako eni kan to fara mo Ajimobi, Ogbeni Olaosebikan Kehinde, nigba to n so pe nnkan to dara ni Ajimobi se.

Opo awon to f’esi le oro re so pe nnkan buruku gbaa ni. Won ni t’ori etanu ati oselu lo se see, won si so pe oro naa yoo yo sile nigba to bay a.

Bee, awon kan n korin ‘E see re ko dara’.

Lara awon to ba Olaosebikan fa surutu lori Facebook ni Adekunle Onile, Asiwaju Gbogbo ati Debo Adeosun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…