Home Orisirisi Ó ṣe, àrùn arunmọléegun ló pa ọmọ Eucharia Anunobi
Orisirisi - August 23, 2017

Ó ṣe, àrùn arunmọléegun ló pa ọmọ Eucharia Anunobi

 

Iru iku to pa omo osere fiimu, Eucharia Anunobi, ti foju han bayii.

Omokunrin kan soso ti osere Nollywood naa ni, Raymond Ekwu, ku ni eni odun meedogun.

Arun arunmoleegun, isyen sickle cell, lo pa omo naa.

Ki Olorun te omo naa si afefe rere.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…