Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ìjọba àpapọ̀ gbẹ́sẹ̀ lé orin Lamide àti Davido
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 22, 2017

Ìjọba àpapọ̀ gbẹ́sẹ̀ lé orin Lamide àti Davido

Ijoba apapo ti gbese le awon orin tuntun kan ti awon osere hip hop kan sese se.

Awon osere ti oro naa kan ni Olamide, Davido, ati 9ice.

Ajo to n ri si eto radio ati telifisan, iyen National Broadcasting Commission, lo gbe igbese naa.

Awon orin ti won ni won ko gbodo na si afefe lori redio ati telifisan ni eyi ti akole re n je WO, lati owo Olamide; WAVY lati owo Olamide; FALL, lati owo Davido ati LIVING THINGS lati owo 9ice.

Gege bi ajo NBC ti so, awon orin naa n gbe iwa ibaje tabi ohun to le fa idaamu ba ilu bii siga mimu ati iwa ofale, laruge.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…