Home LÁGBO ÀRÍYÁ Inú yàrá l’èmi àti Ojopagogo ti máa ń parí ìjà wa – Moji Afolayan
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 20, 2017

Inú yàrá l’èmi àti Ojopagogo ti máa ń parí ìjà wa – Moji Afolayan

 

Toko-taya osere Yoruba meji kan, Rasaki Olayiwola, ti opo eniyan mo si Ojopagogo, ati Moji Afolayan-Olayiwola, ti so asiri ohun to mu igbeyawo won maa dun, to fi n loyin.

Odun 2004 ni won ti fe ara won, leyin ti won pade ni lokesan ti won ti n sere.

Won so fun awon oniroyin pe lati igba ti awon ti fera, awon ko kabamo rara.

Gege bi Moji se so, o ni Olorun ni apata awon, to n je ki nnkan dan moran.

O ni loooto, aremoja kan ko si, ajamore ni ko dara.

O ni nigba miiran, toko-tiyawo le je ki awon to ba nimo ati iriri ju tiwon lo ba won da si ede aiyede to ba wa; o ni sugbon ni ti awon, ti awon ba se ara awon, awon n toro idarijin lowo ara awon, ti awon yoo si wo yara lo, nibi ti awon ti maa n pari ija.

Ohun ti won wa maa se leyin ti ija ba pari ninu yara, ko so fun eni kan.

Ojopagogo ni ara ohun ti o n fun oun ni idunnu lori bi oun se fe Moji ni pe o ni ifarada, o si je eni kan ti kii f’ise sere.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…