Home Orisirisi Buhari n pada si Naijiria lonii
Orisirisi - August 19, 2017

Buhari n pada si Naijiria lonii

Iroyin idunnu kan ti ja lule lati Abuja o.

Won ni Aare Muhammadu Buhari yoo pada si Naijiria lonii.

Atejade kan lati owo Olubadamoran Agba lori Oro Iroyin fun Aare, Ogbeni Femi Adesina, so pe ijoba dupe lowo awon omo Naijiria, paapaa awon to gbadura fun un.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…