Home Orisirisi Obasanjo ju bombu lu awon asofin Abuja
Orisirisi - August 18, 2017

Obasanjo ju bombu lu awon asofin Abuja

.O ni ole ti kii lo ibon ni won

Aare ana, Oloye Olusegun Obasanjo, tun ti ju bombu oro lu awon asofin agba to wa ni ilu Abuja o, o ni ole paraku, jaguda oun barawo ni won.

O ni ogboju ole ni won, won ko kan n lo ibon rara ni.

Obasanjo ni nigba tie bi n pa aimoye omo Naijiria, aon asofin naa kan n bu owo to wu won funra won ni.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…