Home Orisirisi Se ooto ni pe Ooni ti fe iyawo miran?
Orisirisi - August 15, 2017

Se ooto ni pe Ooni ti fe iyawo miran?

 

 

Niwon igba to je pe aponle ko si fun oba ti ko ni olori, Ooni ti Ile-Ife, Oba Adeyeye Eniitan Ogunwusi, ni a gbo pe o ti ni olori miiran bayii o.

Iroyin tan jade ni ana Monday pe olori Ooni tele, Iyaafin Wuraola Ogunwusi, ko si pelu Kabiyesi mo.

Sugbon nigba ti opo eniyan si n ko ‘ Haa’ lori iroyin yi, awon kan tun so pe Kabiyesi ti fe iyawo miran ti won pe oruko re ni Bolanle.

Amo Akowe Iroyin fun Kabiyesi, Ogbeni Moses Olufare, ni iro ni pe ija kankan sele laarin Ooni ati Olori Wuwaola.

O ni alaafia ati ife lo si n joba nile ola o.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…