Home iroyin PDP di àpadàbọ̀ Abìjà – Fayose
iroyin - August 12, 2017

PDP di àpadàbọ̀ Abìjà – Fayose

Gomina ipinle Ekiti ni Aso Rock yen ni oju ohun wa ni odun 2019. O ni bi o tile je pe oun ko le so iye eni to maa ba oun lo sugbon Aso Rock di dandan ni 2019. O n salaye ye yii nibi ipago ti egbe PDP se ni ilu Abuja ni oni ojo Abameta, ojo kejila, osu kejo odun yii. O ni oro egbe PDP maa da bi apadabo Abija ninu fiimu Oloogbe Ajileye, ti Abija wa buru ju ti tele lo.

Fayose ati Femi Fani-kayode ni awon maa gba Naijiria kuro lowo “one Chance” ti won wa. Aare ana, Omowe Goodluck Jonathan ni erin awon egbe APC maa n pa oun ni nigba ti won ba n soro bo se wu won, won ni ti oun ba wa lori aleefa, gbogbo nnkan ko ba ti gbowo lori ju bayii lo.

Jonathan ni gbogbo oro Naijiria ti awon egbe to n se ijoba ti se jaku-jaku ni awon maa da pada ni odun 2019.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…