Home Orisirisi Ise mekaniiki lo wu mi lati se nigba ti mo wa ni kekere – Obasanjo
Orisirisi - August 8, 2017

Ise mekaniiki lo wu mi lati se nigba ti mo wa ni kekere – Obasanjo

 

O ranti ojo to gba tisa leti

Ayanmo ko ni tase. Kadara ko labuye. Gege bee ni ti olori orile-ede yii tele, Oloye Olusegun Obasanjo.

Nigba ti o wa ni omode, ise to wu u ju lati ko ni ise mekaniiki.

O se alaye oro yii ni soosi Diocese of Lagos West, Archbishop Vining Memorial Church Cathedral  ni ilu Eko, nigba to n ranti atimaabo re.

Sugbon o fi kun un pe baba oun ko fara mo o. Baba naa lo ni ko lo si ile iwe.

Obasanjo wa fi kun un pe lojo ti won fe gba oun si ile iwe, oun gba tisa kan leti nitori o beere oruko baba oun.

Igbagbo ti Obasanjo nigba naa ni pe arifin nla gbaa ni pe ki eni kan maa daruko baba re.

Amo o, won fiya je oun naa lojo naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…