Home LÁGBO ÀRÍYÁ Àwọn apanimáyọdá sẹ̀rù ba Mercy Johnson
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 5, 2017

Àwọn apanimáyọdá sẹ̀rù ba Mercy Johnson

Awon eniyan kan ti da ipaya si okan osere fiimu ti a mo si Mercy Johnson, nipa bi won se pe ni ipe kolori-konidii kan lori ero alagbeka.
Mercy Johnson ni nigba ti nomba naa pe oun, o kan soro sakala to ni pipa eniyan ninu.
O ni nigba ti oun pe nomba naa pada, oro buruku lo n so si oun.
Idi niyi ti Mercy Johnson fi fi oro naa to awon olopaa ati EFCC leti.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…