Home Orisirisi Nítorí Doris Simeon, àwọn ọmọ Naijiria sì ń bínú sí Stella Damasus
Orisirisi - August 1, 2017

Nítorí Doris Simeon, àwọn ọmọ Naijiria sì ń bínú sí Stella Damasus

Awon omo Naijiria kan so oro kobakungbe si osere fiimu ti a mo si Stella Damasus lonii, to je ojo ti baale re, Daniel Adenimokun, n se ojo ibi re.

Wahala bere nigba ti Stella ki okunrin naa ni mesan-an mewaa, to si so pe oun ko tii ri iru ife to wa laarin awon ri.

Ase iyan ogun odun a si maa jo eniyan lowo. Abi bawo la se fe pe inu abiibitan ti opo awon omo Naijiria si obinrin yii. Ni idahun si oro ti Stella so, opo awon eniyan ni kii se eeyan dada. Won ni nnkan buruku lo se nipa gbigba oko Doris. Won ni ohun to wa buru ju nip e Stella ati Daniel si mu omo kan ti Doris bi fun un sodo, ti won ko je ko wa pelu iya re.

Sugbon bi awon kan se n bu u, ni awon kan n gbija re. Won ni kii se ese ki eniyan fe eni to ba wu u, paapaa nigba ti ko fi ipa gba okunrin naa mo Doris lowo.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…