Ìdánrawò
Ẹ kọ ohun tí ẹ lérò pé àwọn Sẹ́nétò méjì yìí ń sọ. Ẹni àkọ́kọ́ ni Sẹnatọ Ademola Adeleke tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ dìbò yàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun nígbà tí ẹni kejì jẹ́ Sẹ́nátọ̀ Dino Melaye ti ìpínlẹ̀ Kogi.
Kín ni ìyọra wọn?
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…