Home iroyin Àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun sì ń nífẹ̀ẹ́ ẹbí mi – Ademola Adeleke
iroyin - July 29, 2017

Àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun sì ń nífẹ̀ẹ́ ẹbí mi – Ademola Adeleke

Seneto ti won sese dibo yan ni ipinle Osun ni o n ba awon oniroyin soro ni ilu Abuja leyin ti won se ibura fun un tan. Alagba Femi Adesina gba a lalejo, o si salaye fun un pe jijawe olubori re fi apeere ijoba awa-ara-wa tooto han.

Ademola Adeleke naa si fi kun un pe, laarin ojo kan pere ti oun kuro ni egbe kan si egbe miran, awon eniyan si tele oun lo, ni eyi to se afihan iwa daadaa to wa ninu ebi Adeleke. O ni lai ti si ni ijoba ni ebi Adeleke ti n se opo nnkan ti ijoba ko lee se. Awon nnkan bii eto eko ofe, ironi-lagbara ati bee  bee lo.

O si tun seleri wi pe wiwole si ipo Seneto oun yii tun maa je ki awon eniyan je anfani oun ati ebi Adeleke daadaa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…