Home Orisirisi Asari Dokubo gbé Don Jazzy s’épè
Orisirisi - July 29, 2017

Asari Dokubo gbé Don Jazzy s’épè


Okan lara awon ajajagbara Niger Delta, Asari Dokubo, ti di epe rugudu ru gbajugbaja akorin ati onise orin, Don Jazzy.
O ni Olorun ni yoo fiya je lapalapa, ka ma daruko Don Jazzy si i.
Bakan naa o ni Olorun ko ni fori jin Aremu Afolayan ati awon eniyan miiran ti won ti bu enu ate lu Deizani Alison-Madueke, latari owo goboi to ji ko mo Naijiria lowo.
Dokubo daruko awon olori Naijeria kan, o si ni awon naa ti ji owo nla, ti eni kankan ko si bi won.
O war o pe bo ti wu ki Deizani ji owo to, ko ye ki eni kankan ba a ja si i.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…