Home iroyin Àbúrò Kúnlé Afọlayan s’épè ńlá fún Deizani
iroyin - July 27, 2017

Àbúrò Kúnlé Afọlayan s’épè ńlá fún Deizani


Ko nii daa fun Deziani – Aburo Kunle Afolayan da epe bole
Bi Aremu Afolayan, to je aburo onifiimu Kunle Afolayan, ba fi oju kan Minisita fun Oro Epo Robi tele, Iyaafin Deizani Madueke, afaimo ni ko ma di igbaju ru u.
Koda, Aremu Afolayan lee na a ni ponpo.
Inu buruku lo n bi arakunrin naa, leyii to da leri asiri nla nla to n tu sita lori bi obinrin naa se ji owo Naijiria.
Asipaya iroyin to n waye ni oke okun fihan pe bi Sanni Abacha se ji owo ni ajiijitan ni Deizani naa se ji i.
Eyi lo fa a ti Aremu Afolayan se fi epe buruku bonu lojo Alaaruba, to n so pe ko nii daa fun Deizani. O fee maa so pe bi Alale ba ni ko dara fun un, Alaaro ko ni se ami.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…