Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ọlọ́run ti gbémi lékè àwọn tó ní n kò lè fi òyìnbó kọrin – Dekunle Gold
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 26, 2017

Ọlọ́run ti gbémi lékè àwọn tó ní n kò lè fi òyìnbó kọrin – Dekunle Gold

Akorin Orente, Adekunle Gold, ti se arojinle lori irinanjo re ninu ise orin kiko.
Paapaa, o dupe lowo Olorun lori awo orin re, ti akole re n je GOLD, eyi to ti pe odun kan to gbe jade.
O ni okan oun ko bale nigba ti oun fe gbe orin naa jade, sugbon ope, idunnu ati ayo lo ja si nigbeyin.
Dekunle ni nigba kan, awon kan bu enu ate lu orin oun; o ni won so pe orin Yoruba lasan ni oun n ko.
Sugbon bayii, o ni ati Hausa, Igbo ati oyinbo lo n ko orin oun, ti won si n jo si i.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…