Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Okorocha láálí Fani-kayode, ó pè é ní àkẹ́bàjé ọmọ
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 25, 2017

Okorocha láálí Fani-kayode, ó pè é ní àkẹ́bàjé ọmọ


Gomina Ipinle Imo, Alagba Rochas Okorocha, si so oro kobakungbe si Minisita fun Oro Oko Ofurufu tele, Oloye Femi Fanikayode.
O ni akebaje, oju-o-rola-ri omo lasan ni.
Okorocha fibinu so oro yii ninu atejade kan ti Akowe Iroyin re, Sam Onwuemeodo, gbe jade lonii.
O so eyi lati fesi si yeye ti Fanikayode fi Okorocha ati awon omo egbe APC to lo ki Buhari ni London se.
Fanikayode ni alainitiju ati oniro ni won.
Gege bi Okorocha se so, o ni Fanikayode ko ni ise kan gbogi to ti se ri, ati pe owo baba re to ba nile lo n gun un gaagaa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…