Home iroyin Ìjọba àpapọ̀ fẹ̀mí ìmoore hàn sí Sójà Boko Haram
iroyin - July 25, 2017

Ìjọba àpapọ̀ fẹ̀mí ìmoore hàn sí Sójà Boko Haram

Oni ojo Tuside ni ijoba apapo ni ti “a ba seni loore ti a ko dupe, yoo dabi igba ti olosa keru eni lo”. Ijoba se igbega lenu ise fun awon Soja ti won ti n femi won wuwu lati odun ti awon Bako Haram ti n sose ni ile Hausa.

Oruko ti awon Soja yii fun ara won ni “Lafia Dole” ti o tumo si pe dandan ni alaafia. Awon Soja to le ni egberun mefa ni ijoba apapo se orisiirisii igbega fun ni aaro oni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…