Home ÀKỌ̀TUN Àìsàn kankan kò ṣe Abu Olódodo kó tó kú – Waidi Ijaduade
ÀKỌ̀TUN - July 24, 2017

Àìsàn kankan kò ṣe Abu Olódodo kó tó kú – Waidi Ijaduade

IJADUADE

Okan lara awon onifiimu Yoruba, Waheed Ijaduade, to je ore Olurotimi Josiah Ayinde (Abu Olododo), ti so pe iku ojiji ni okunrin naa ku.
Iku Abu Olododo, to je osere Yoruba, sese n tan kale ni, bi o tile je pe a si n sedaro Alagba Adebayo Faleti lowo.
Gege bi Ijaduade so so, o jo pe oru Sunday ni Abu Olododo ku.
O ni Abeokuta ni awon jo n gbe, ti awon si maa n lo sile ara won.
Ijaduade ni oun wa ni ile Abu Olododo lojo Sunday, ti ko si si arun Kankan to se e .
O ni awon ni awon fi ipade kan ni oni Monday paapaa, laimo pee mi ti ko ni dola lo n da osu metala.
Osere naa so pe ko si oun to se Josiah to fi sun lale Sunday. Sugbon nigba to di aaro Monday ti awon ara ile re ko ri i ko jade sita lati inu yara ni won lo kan ilekun re.
O ni igba naa ni won ba a lori aga to joko le, to si ti ku sibe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…