Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Owo PSG ti fe di Neymar leti, ko gbo oro Barcelona mo
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 23, 2017

Owo PSG ti fe di Neymar leti, ko gbo oro Barcelona mo

Owo nii ba oju ore je. Gege bee ni oro egbe agbaboolu Barcelona ati Neymar bayii. Owo tabua 196 million pounds ti PSG fe gbe fun agbaboolu naa ko je ko gbo I koosi Barca mo.
Won n ba a se ipade pe ko duro si Barca, sugbon o jo pee yin eti re ni gbogbo oro won n bo si.
Ti oro ba ri bee, o je pe Barca n lati wa elomiran ti yoo jo maa pari ise niwaju pelu Messi ati Suarez niyen.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…