Home LÁGBO ÀRÍYÁ Òkú Adébáyọ̀ Fálétí, òkú gbogbo wa ni – Jide Kosoko
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 23, 2017

Òkú Adébáyọ̀ Fálétí, òkú gbogbo wa ni – Jide Kosoko

 

Agba osere, Alagba Jide Kosoko, ti sedaro eekan nla ninu awon alariya, Alagba Adebayo Faleti, eni to di oloogbe ni aaro yii.

Alagba Kosoko ni eniyan gidi gbaa ni Faleti je. O ni o je agba daadaa ti kii se abosi. O ni ki fi dudu pe funfun fun eni kankan.

Jide Kosoko fi kun un, “Eni iyi, eni eye ni Baba Faleti je. Ko se abosi kankan laarin awa taa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…