Home iroyin Okorocha àti Oyegun kó ikọ̀ sòdí lọ kí Ààrẹ Buhari ní London
iroyin - July 23, 2017

Okorocha àti Oyegun kó ikọ̀ sòdí lọ kí Ààrẹ Buhari ní London

 

Olori awon gomina egbe oselu APC, Rochas Okorocha ati olori egbe oselu naa Odige Oyegun ko iko sodi lo si orileede London lati lo se abewo si Aare Buhari. Won fi foto ti won jo ya ni ibi ti won ti n jeun ranse bi won se debe.

Okorocha ba Femi Adesina soro ni Naijiria lati koko fi wa lokan bale pe saka ni ara Aare Buhari da. Won ni gbogbo iro ti awon eniyan kan n gbe kiri nipa pe Buhari ko le soro mo ati pe aisan naa ko je ko le ro arojinle mo. Won ni iro pata-pata to jinna si ooto ni eyi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…