Home iroyin Àbí Mercy Aigbe àti Lanre Gentry ti parí ìjà wọn?
iroyin - July 20, 2017

Àbí Mercy Aigbe àti Lanre Gentry ti parí ìjà wọn?

Oro oko pel’aya
Aye e ma ma da si
Ko to p’osu mefa
Aa pari o…
Orin Ebenezer Obey yii lo wa si wa lokan nigba ti a gburoo pe Mercy Aigbe ati baale re, Lanre Gentry, ti pari ija won.
Koda, a ti n ri awon foto won kan nibi ti won ti n je ete.
Ti Olorun ba je ko ri bee, iroyin idunnu ni eyi maa je fun awon ololufe tokotiyawo. Eyi yoo si tun ko opo eniyan lekoo oe nigba ti oko ati iyawo ba n ja, ki eeyan maa so ohun ti yoo so. Bi bee ko, ori oluware ni won yoo yi i nnkan le lori.
Bi osu meji seyin ni ija nla be sile laarin Mercy ati Lanre. Obinrin naa ni alupamokuu ni Lanre maa n lu oun. Sugbon okunrin naa ni ko ri bee. Oro naa wa ni kootu bayii.
… Oro ko ri bee
Sugbon sa o, awon kan ti won sun mo Mercy ti so pe ija naa ko tii pari. Won nib o se wa naa lo wa.
Gege bi won se so, won ni awon foto ti o wa nita wa lara eyi ti won ti ya tele.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…