Home Orisirisi Ambode fọ̀nà ìta han Baalẹ Sangisa
Orisirisi - July 13, 2017

Ambode fọ̀nà ìta han Baalẹ Sangisa

Gomina ipinle Eko, Akinwunmi Ambode ti fi ona ita han AlagbaYusuf Ogundare to je Baale ilu Sangisa ni Ipinle Eko. Baale yii jebi esun lilu jibiti ajinigbe ni eyi to bo si ibinu fun gomina. Ambode ni ijoba oun ko ni fi aaye gba gbogbo ohun to le je iwa alumokoroyi tabi iwa ibaje kankan, paapaa julo lodo iru awon ti o ye ki o je awokose fun awon ilu ti won tun wa n gbeyin bebo je.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…