Home LÁGBO ÀRÍYÁ Prayer warrior ni ìyàwó mi – Ali Baba
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 11, 2017

Prayer warrior ni ìyàwó mi – Ali Baba

 

Gbajugbaja alawada ti a mo si Ali Baba ti so asiri awon nnkan to je ki oro iyawo re, Iyaafin Ochuko Ali Baba, o wuwo lokan re.

Gege bi Ali Baba ti se afihan re lonii, o ni eni kan to le gbadura gidigidi ni, eyi ti awon elesin Igbagbo n pe ni prayer warrior.

Ko tan sibe o, Ali  Baba ni obinrin naa je olubadamoran oun pataki. O ni o je eni kan to je pe o maa n se agbeyewo awada ti oun ba fe se, ki oun ma baa fenu ko. Bee, o ni o tun Ochuko tun maa n se alukooro ati agbodegba fun oun, eyi ti o pe ni Public Relations Manager.

Ni akotan okunrin naa so lori Twitter pe ololufe pataki ni Ochuko je si oun, ati pe abiamo rere ni.

Ali Baba yombo iyawo re nigba ti o n ki i ku oriire ojobii re to waye ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…