Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ọ̀rọ̀ Naijiria ti sú mi pátápátá – Mocheda
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 10, 2017

Ọ̀rọ̀ Naijiria ti sú mi pátápátá – Mocheda

 

O tip e die ti opo eniyan ti gburo akorin hip hop ti a mo si Mocheda.

Loooto, nnkan ko dan moran fun un to mo. Nigba to koko jade ni nnkan bii odun mefa seyin, opo eniyan ro pe yoo gbajoba mo awon Tiwa Savage lowo ni. Sugbon, oro ko ri bee.

Ni bayii, omodebinrin naa ti oruko re gan-an n je  Modupe-Oreoluwa Oyeyemi Ola ti so pe oro Naijiria ti su oun pata.

O ni awon ijoba ko wulo, bee opo awon eniyan gan-an ko le ja fun eto won.

O fi kun un pe awon ewe ko se arojinle lori ohun to n sele lorile ede yii debi pe won yoo gbe igbese gidi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…