Home Orisirisi Oju yoo ti awon eranko to so pe Buhari ko ni de layo – Aisha
Orisirisi - July 10, 2017

Oju yoo ti awon eranko to so pe Buhari ko ni de layo – Aisha

 

Iyawo Aare, Iyaafin Mohammadu Buhari, ti fi enu re epe ati isokuso danu lori baale re; se, enu eni la fii ko ‘meje’.

O ni awon eranko buruku bii eyi ti awon oyinbo n pe ni hyena, ti won n sa kuku-keke ni Naijiria tori baale oun, ti won fe maa pin ogun alaaye, oju yoo ti won nigba ti oninkan ba de.

Aisha so eyi nigba ti o n da Senito kan, iyen Shehu Sanni, lohun lori ohun ti o so nipa Buhari.

Sanni ni gbogbo bi awon hyena naa se n sa kuku-keke lati gba ogo mo Buhari lowo, eni oro kan naa ko le dide, ko le soro ki awon eniyan le mo bawo ni n kan se rig an-an.

Sugbon Aisha, eni to lo si London lati wo Buhari, so pe adura ti gba, ati pe awon ehanna eranko yoo gba idojuti laipe yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…