Home iroyin E ye fiya je olopaa, se loooto ni ko si jenereto ni bareke Iyaganku?
iroyin - July 10, 2017

E ye fiya je olopaa, se loooto ni ko si jenereto ni bareke Iyaganku?

 

Alagba kan to maa n gbe asa ga, to tun je akoroyin pataki, Alagba Wale Ojo-Lanre, ti ke si awon ijoba Naijiria ati alase awon olopaa pe ki won ye fiya je awon agbofinro wa.

O ni ohun ti Naijiria n foju won ri, paapaa ni bareke won, ko dara to.

O se apere igba ti oun koja ni bareke olopaa kan to wa ni Iyaganku ni Ibadan, ni ale ojo kan laipe yii, to si je pe okunkun birimu birimu ni won wa nibe.

O ni dipo ki won tan jenereto, lanta lasan ni won tan, eyi to wo o pe ko bojumu rara.

Bi a ba woye daadaa loooto, a yoo ri i pe a kan maa n bu awon olopaa ni, Naijiria naa ko maa se ohun to ye fun won.

Owo osu ti won n gba kere. Won maa n fie to won dun won, debi pe ko si ohun amayederun ni opolopo awon bareke won kaakiri Naijiria.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…