Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mosun Filani ń jèrè ìgbéyàwó, ó kọrin ìfẹ́ fún baálé rẹ̀
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 6, 2017

Mosun Filani ń jèrè ìgbéyàwó, ó kọrin ìfẹ́ fún baálé rẹ̀

 

Nibi ti awon osere kan ti n foju wina ni ile oko won, orin ayo ni Mosun Filani n ko laaro ati lale o.

Idi nip e alaafia nla n joba ninu ile oun ati Alagba Aakoye Filani, eni to pe ni alatileyin oun nla.

Gege bi oro ti Mosun so, o ni Alagba Kayode ni aaro meta ti ko je ki obe idunnu oun da sina. O ni Kayode ni ejika oun ti ko je ki eru o ye danu.

Nigba ti Mosun n se ayeye ojo ibi re pelu awon aramanda foto to ya, o dupe gidi lowo Olorun, tori o nigbagbo pe aanu Olorun ni oun rigba ti nnkan fi n dan moran fun oun.

Adura IROYIN OWURO nip e esu ko ni wole won o.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…