Home ÀRÒJINLẸ̀ Àjekún ìyà apá kejì
ÀRÒJINLẸ̀ - July 5, 2017

Àjekún ìyà apá kejì

Oro ti a ro pe o ti ku regbe, ti opo si tun ro pe o ti ku regbe ma ti wu jade bayii. Awon ajo eleto idibo ile wa (INEC) ti gbe ate ise lori bi won se maa dibo lori esun ti awon ara agbegbe ipinle Kogi West fi kan asoju won Dino Melaye.

Awon ara agbegbe naa ko iwe enini lati pe asoju won wale, won ni ko soju awon daadaa. Gbogbo omo Naijiria lo si ti n reti awo orin Melaye ti o ba lo jawe olubori nibi idibo naa tabi idakeji.

Ti a ko ba gbagbe, Melaye lo ko orin “ajekun iya” nigba ti awuye-wuye wa lori esi idanwo re, ti ero igbalode si tan awo orin naa kaakiri agbaye. Eyi lo faa ti awon eniyan tun fi n reti awo orin miran to ba jawe olubori. Inu osu kejo ni awon eleto idibo ni awon maa kede ti Melaye ba maa pada wale tabi o si maa duro si ile igbimo asofin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…