Home LÁGBO ÀRÍYÁ Tọ́pẹ́ Àlàbí rántí ọjọ tí àwọn jàǹdùkú fẹ́ fipá bá a lòpọ̀
LÁGBO ÀRÍYÁ - June 25, 2017

Tọ́pẹ́ Àlàbí rántí ọjọ tí àwọn jàǹdùkú fẹ́ fipá bá a lòpọ̀

 

 Eni ti yoo ga, ese re yoo tin-in-rin. Gege bee ni ti gbajugbaja akorin emi, iyen Tope Alabi.

O so awon ohun ti oju re ri nigba ti o wa ni omode, paapaa nigba ti o si wa labe asia awon obi re.

Telo 9tailor) ni baba Tope Alabi nigba to wa laye, ti o si je pe baba naa ati iya re ni won lakaka ninu ofii, ninu olaa lati pese jije ati mimu.

Sugbon sa o, Tope Alabi ni bi nnkan se le fun awon to, iya oun ko oun ni eko gidigidi lori bi omobinrin se gbodo maa pa ara re mo, ti ko ni ya aja tabi omo ganfe lori pe o n wa owo.

O ni iru eko naa wulo fun oun lojo kan nigba ti awon omo jandudku kan fe se were fun oun.

O ni lojo naa, ni nnkan bii aago meje aabo asale, iya oun ran oun nise lo si ibi kan.

Awon omokunrin naa wa ko ara won jo, won lo dena de oun, ti won si fe da oun dubulelati fi ipa ba oun lopo, eyi ti awon oyinbo n pe ni gang raping.

Ninu iforowanilenuwo kan, Tope Alabi ni oun sa are asadiju, ti oun si n pariwo apaadake.

O ni bayii ni oun se bo lowo awon karandaani naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…