Home ÀṢÀ ÀTI ÌṢE Mo máa ń lọ gbàdúrà ní mọ́sálásí – Ọọni
ÀṢÀ ÀTI ÌṢE - June 25, 2017

Mo máa ń lọ gbàdúrà ní mọ́sálásí – Ọọni

 

Ooni ti Ile-Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ti so pe oun maa n lo ba won josin ni mosalasi, bi o til je pee sin ti omoleyin Kirisiti ni won bi oun si.

Kabiyesi ni oun maa n lo gbadura ni mosalasi, oun n se ijosin ati adura ni soosi; bee oun tun maa n ba won se esin ibile.

Ooni ni esin meteeta ni oun n se tori oun ti ri oye pe Olorun kan soso ni gbogbo won n ke pe.

Inu fidio kan to jade lojo Satide ni Ooni ti so oro naa.

 

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…