Home Orisirisi CCT: Òwe márùn-ún tó bá ìdájọ́ Saraki mu
Orisirisi - June 14, 2017

CCT: Òwe márùn-ún tó bá ìdájọ́ Saraki mu

Ile ejo Code of Conduct Bureau  to  gbejo esun aisooto nipa dukia ti Aare Ile Asofin Agba, Dokita Bukola Saraki, so pe oun ni da senito naa lare lanaa (Ojo Alabuba).

Idunnu nla ni idajo naa je fun Saraki ati awon eniyan re.

Eyi mu ki o dupe gidi lowo Olorun, awon adajo ati awon akegbe re ni Seneeti, lori bi won se se atileyin fun un nigba ti oju ogun le.

Sugbon iyalenu nla ni idajo naa je fun opo eniyan, tori won gba pe awon esun ti won fi kan Saraki naa wuwo debi pe ko ye ki won dede daa sile bee.

Bi won se wa da Saraki lare naa, ati oro to n jeyo leyin re mu IROYIN OWURO ranti awon owe Yoruba kan:

  1. Bi eegun ba n leni, ka maa roju. B’o se n re ara aye lo n re ara orun.
  2. Bi iro ba lo l’ogun odun, ojo kan ni otito yoo ba a .
  3. Atebi, atare, Olorun ma je ka r’ejo.
  4. ‘Ko soju mi’ kii pe ni kootu.
  5. Opolo ni ti a ba soro debi iru, k’a fo o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…