Home Orisirisi Àsìlò oògùn àti ọtí àmujù ló pa Adeleke – Ayilara
Orisirisi - June 10, 2017

Àsìlò oògùn àti ọtí àmujù ló pa Adeleke – Ayilara

 

Onimo ijinle to dari ayewo lori iku to pa Gomina Ipinle Osun tele, Snito Isiaka Adeleke, Ogbeni Olusegun Ayilara, ti so pe eni kankan ko fun Adeleke loogun je.

O ni iwadi ti awon se fihan pe ko si majele ninu ara re.

Dipo bee, o ni noosi puruntu to fun Adeleke ni abere nigba ti aare mu un lo da wahala sile nipa fifun un ni oogun lile ti ko ye ko fun un.

O ni noosi naa, Alfred Aderibigbe, je eni ti o ti maa n sise ilera fun Adeleke fun bii ogun odun. O ni sugbon lojo ti isele naa sele, oogun ti ko ye ko fun un lo fun un.

Bakan naa, Olatunji ni awon ri i pea silo naa ba amuju oti ninu ara oloogbe naa.

Ijoba Ipinle Osun lo gbe iwadii naa kale.

Ebi Adeleke naa se iwadii tiwon, sugbon ti won ko tii gbe esi jade

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…