Home Orisirisi Iranlowo banki lo le segun awon ole ijoba – Osinbajo
Orisirisi - June 5, 2017

Iranlowo banki lo le segun awon ole ijoba – Osinbajo

Adele Aare Ile wa, Ojogbon Yemi Osinbajo ni agbepo laja, ko jebi bi eni to gbaale.

Osinbajo ni to a ba fe gbogun ti iwa ibaje daadaa. Awon ile-ifowopamo-si gan-an ni ipa to po lati ko. O ni won ni lati maa tu asiri gbogbo awon to ji  owo ilu, ti won si koo pamo si odo won.

Ilu Abuja ni Osinbajo ti n salaye yii. O ni igi kan ko le da igbo se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…